OOGUN TI A FI N GBA ETO WA LOWO ENITO KO TI KO FE FUN WA TO DAJU

Описание к видео OOGUN TI A FI N GBA ETO WA LOWO ENITO KO TI KO FE FUN WA TO DAJU

A ma n fi asiri yi gba owo lowo eniti ko fe fun wa, ti a si mo wipe owo wa ni owo iru eni bee, mo wa be wa ni oruko olohun oba be wa wipe ki a ma se lo asiri yi ni ona aito, looto awon asiri po ti won n se iru ise bayi, e ma je ki a lo awon asiri naa ni ona ti ko dara nitoripe wipe nkan to ko oju si taye loni le pada ko eyin si lola, e je ki a danwo asiri to daju to sise daada ni

Комментарии

Информация по комментариям в разработке