OKAN MI NYO NINU OLUWA

Описание к видео OKAN MI NYO NINU OLUWA

1. Okan mi nyo ninu Oluwa
‘Tori O je iye fun mi
Ohun Re dun pupo lati gbo
Adun ni lati r’oju Re

Egbe
Emi nyo ninu Re (Oluwa)
Emi nyo ninu Re
‘Gba gbogbo lo nf’ayo kun okan mi
‘Tori emi nyo n’nu Re

2. O ti nwa mi pe ki nto mo O
‘Gba ti mo rin jinna s’agbo
O gbe mi wa sile l’apa Re
Nibiti papa tutu wa

Egbe
Emi nyo ninu Re (Oluwa)
Emi nyo ninu Re
‘Gba gbogbo lo nf’ayo kun okan mi
‘Tori emi nyo n’nu Re

3. Ire at’anu Re yi mi ka
Or’ofe Re nsan bi odo
Emi Ri nto, o si nse ‘tunu
O mba mi lo si ‘bikibi

Egbe
Emi nyo ninu Re (Oluwa)
Emi nyo ninu Re
‘Gba gbogbo lo nf’ayo kun okan mi
‘Tori emi nyo n’nu Re

4. Emi y’o dabi Re nijokan
Ngo s’eru wuwo mi kale
Titi d’igbana ngo s’oloto
Ni sise oso fade Re

Egbe
Emi nyo ninu Re (Oluwa)
Emi nyo ninu Re
‘Gba gbogbo lo nf’ayo kun okan mi
‘Tori emi nyo n’nu Re

Комментарии

Информация по комментариям в разработке