Adura Ori 1,Yoruba prayer for the head. Connect inner head to Olodumare 3 am daily.

Описание к видео Adura Ori 1,Yoruba prayer for the head. Connect inner head to Olodumare 3 am daily.

Ninu ogbologbo odun yi ati odun ti o nbo,
In this aged year and years to come
Oni kawo l'eri sunkun o, o ni fara gbaruwe
You shall not place hand on head wailing.
Mo tewo ire, mo sure mo ka leri,
I spread palms of goodnes, I invoke goodnes and fold it on my head.
Ogun ikawoleri, fese janle ninu ile ko ni sele s"eni kan kan wa.May we not be embattled by sorrow
Ori mi ape abara le koko bi ota, ori mi ape
Ki ibi o ma se ba mi ko ma se ba e.
Ori mi ape abara le koko bi ota, ori mi apesin ki ibanuje o ma se wole to wa.
Ori mi ape a bara le koko bi ota ori mi apesin, ogun ekun ogun ose ko ma se ba mi ko ma se ba e. Se bi eni ti ori ba gbe lo n ba won gbe ile aye sehun gidi
Ori mi o, eleda mi, se iwo ni mo fi siwaju l'aye ni mo n tele e, mase je n bawo tayo laije l'aye mo wa o,
Oba tete la kori olola ma se pe e ran nise.
Ori dagbe o se ti e ni Kiki aro,
Ori da aluko o se ti e ni Kiki osu,
Ko ni tan ninu igba osu ka ma ri fi pa omo l'ara.
Gbogbo igba ti a ba n ki owo b'apo ki a ma ri na ka ma ri lo.
Ori to da leke leke o se ti e ni Kiki efun,
ki aso o ma se pon mo wa l'orun. Ori mi gbe mi k'ewu o ma se ya mo mi l'ejika.
Ori mi gbe mi, se bi ori l'eja fi n la ibu ja
Ori lakere fi n se ti e l'oto l'abata.
Ori mi gbe mi o, ori l'eja fi n la ibu ja,
Ori l'obi fi n se ti e lara oto l'abata,
Ori mi gbe mi o, ori l'agbo fi n kan akan la
Ki lleku ola ko si, ilekun ola ko ma se ti
Ori mi gbe mi o ki ilekun owo ko si
Ilekun ola ko ma se ti
Ori mi gbe mi, ori l'agbo fi n kan akanwo.
Ori mi gbe mi ki n wole ola ki n wole ola
Ki n wole owo nitori eni t'ori ba gbe lo n se ohun gidi ni ile aye
Ori gbe mi, eni ti ori ba gbe a ba won d'ade owo, a ba won de aburo oje,
a ba won te'pa ile ke.
Ori mi gbe mi o
Ki n ri batise ki n ri ona gbe gba
Nitori oba kan o le dani ro
Oba kan o le gbe ni la afi eledumare Oba
Nitori ika fefe la n feye, iwoyi fefe la n lo igba
Bi a ba wa foye logba bi o ba dun nko,
A sa to eledumare Oba lo mo ri mori ti n mori omo titun, omoran to n mo ori inu eda,
K'ori inu mi o ma se ba ti ode mi je
Ki ori ode o ma se ba tinu je
Ori mi gbe mi o, se bi ori lonise eni, eda ohun ni oloro eni. Gbogbo ibi ti won ba ti n ta ofa ibi ki o ma pada lo ba won, nitori wipe omi ti a ba da s'ori ile lo n bo.
Gbogbo epe ko ma pada lo ba elepe
nitori ti ewure ba b'oju wehin a fi epe felepe,. Bi aguntan ba boju wehin, a f'epe felepe,
Gbogbo eni to ba t'afa ibi ko ma lo, ko pada ko ma lo ba won.
Gbogbo eni to ba n tafa ibi, ko yi pada ma lo ba won.
Ori mi gbe mi o, ori mi gbe mi
tori ikawo o laso ori eni ni n gbe ni
Ori mi gbe mi o gbogbo ohun ti mo ba dawo le ko ma yori si rere, ori mi gbe mi.
Ori mi o, ori mi gbe mi,
Nitori ati orun ni obirin ti n m"ori wa aye, ti won n dele aye ti won n yan oko rere,
Ori mi gbe mi ki n mase si yan
Atorun l'okunrin ti n m'ori w'aye ti won n dele aye ti won n yan aya rere.
Ori mi gbe mi, ma je n si yan.
Ori mi o, eleda mi o
Se wo ni mo fi siwaju l'aye ti mo n tele e
Mase je n bawon tayo lai je l'aiye mo wa o
O ba tete la kori olola ma se pe e nise
Ori mi durotimi, ori mi ape, ori mi apesin abara le koko bi ota,
Ori mi ma se fimi sile lo
Eda mi mase gbagbe mi, ki ori olola ma se pe o ran nise,
Ki gbogbo aye ma so wipe, ki gbogbo ota ma so wipe,
Mi o mo ibi olori gbe yan ri o
N ba le yan temi,
Ng o mo ibi Adeyinka yan ri o
Mba de yan temi, sebi kadara o papo ni,
Emi o mo bi Adeyinka yan ri o
Mba de yan temi.
Ori mi durotimi o, ori mi mase fi mi sile ,
Ori to da agbe, o da sile aro,
Ori to daluko, o da sile osun,
Head created purple woodcock who flourish in dye
Owa da lekeleke o fi gbogbo ti e s'efun
He created the Cattle egret, who flourish with white earth (kaolin)
Ori mi gbemi ,
My head, may you support me.
k'aso o ma se pon mo mi l'orun,
That my worn dress not be filthy in dirt
k'aso o mase ya mo mi l'orun,
That my worn dress not be rags.
That my dress not be filthy with dirt
Ki ise mase di ise,
That my work not become poverty.
Ori mi gbemi o nitori oba kan o le dani ro,
My head, support mi because no king can singly make one stand.
Ori lonise eni, eda loloro eni
Head is one's active partner, destiny is one's discussions partner.
Ori mi gbe mi o ooo
My head, support me(emphatically)
Ori mi gbee miii
My head support me.
My head May you support me
Ki ori inu wa o ma se ba t'ode wa je o
May my inner head not destroy my outer one
A o ni ibanuje o, ekun ose ko ni wo inu ile to
May we not see sorrow, bitter cry, hisses shall not come visiting
wa lodun yi ati lodun to n bo,
This year and in coming years
ire owo, ire ola ire ola ko ma ba gbogbo wa gbe..
Goodness of money, goodness of wealth, of breakthroughs shall dwell with all of us.
lati wakati yi lo ati titi lai lai, kori be ko de se be.
From this hour and for ever and ever, it shall be so, it shall cut through.
Contact email:[email protected]


https://adeyinkaakinwande.simdif.com

Комментарии

Информация по комментариям в разработке