CCC HYMN 708 - EMI NI BABA TO DA NYIN | YORUBA

Описание к видео CCC HYMN 708 - EMI NI BABA TO DA NYIN | YORUBA

CCC HYMN 708 YORUBA


1. Emi ni Baba to da nyin,
Ati awon baba nyin,
Ta le ni na to le da nia?
Ta o le ridi ise Mi?

2. E mura fun ‘sura yin,
Ti kokoro ko le je,
Apanirun ko le de be,
Ere aiyeraiye ni.

3. Eyi sa ni ‘sura yin,
Iwa ati esin yin,
Eyi ni yio gba yin la,
Laiye yi ati l’Orun.

4. Eyin omo ‘Jo Mimo,
E mura ke le r’ogo,
Ti Baba ti pese fun yin,
Ayo aiyeraiye ni.

5. Halleluya Halleluya,
Hossanah s’Oba Mimo,
Halleluya l’orin wa yi,
Yio je l’ojo ‘kehin yi.

6. Awamaridi ni,
Ise Baba wa Orun,
T’oda enia s’aiye yi,
Ati eranko igbe.

7. Ogo, ogo, ogo, ogo,
Fun Baba Metalokan,
B'Oti wa latete kose,
Beni yio ma ri titi.

Amin.

‪@cccSanctumParish‬
‪@cccsharonparish‬
‪@cccakokaparish‬
#cccworldwideofficial
#ccc
#ccchymns
#hymns
#choir
#gospel

Комментарии

Информация по комментариям в разработке