Koko Zaria naa ti sọrọ o.... nipa Lawori onitiata to sọ pé awọn ọmọ ẹyìn ẹ ló fọ́gò mọ òun lórí

Описание к видео Koko Zaria naa ti sọrọ o.... nipa Lawori onitiata to sọ pé awọn ọmọ ẹyìn ẹ ló fọ́gò mọ òun lórí

wahala rẹpẹtẹ laarin awọn onimọto l'Ekoo...wọn loun naa ló fà sababi igo ti wọn la mọ Lawori onitiata lórí o loju agbo

Комментарии

Информация по комментариям в разработке