Itan Basọrun Gaa 2 (video)

Описание к видео Itan Basọrun Gaa 2 (video)

Apá keji Itan Basọrun Gaa ni alaye lori bí Basọrun Gaa ṣe gba ìjọba Ọ̀yọ́ pelu bí ó ṣe pa Alafin Awonbioju pelu bí ó ṣe lo agbára láti gba Ilẹ̀ Togo Dahomey àti Asanti fún Ilẹ̀ Yorùbá
Laji Abbas Whatsapp ++2348023687432 +2348032855888

Комментарии

Информация по комментариям в разработке