Itan Lehin Ogun Osogbo 4

Описание к видео Itan Lehin Ogun Osogbo 4

Apá kẹrin yí jẹ alaye nípa bí Aláàfin Atiba ṣe ranse si Iba Oluyole Ìbàdàn láti gba ilẹ̀ Èkìtì kúrò lábẹ́ Fulani Ilorin lẹhin ti wọn ti gba àmọ́ dibo kí Iba Oluyole se bẹ ìjà Aláàfin Atiba lo ń wá lèyí to pápá wá kan Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfo Kurunmi Ijaiye, dípò kí àwọn olórí mẹtẹta pawọpọ bá ọ̀tá wọn jaa ara wọn ni wọn fẹ dojú kọ.
Laji Abbas Whatsapp +2348023687432

Комментарии

Информация по комментариям в разработке