Ose Ose Rere CAC GH 59/HMYNS

Описание к видео Ose Ose Rere CAC GH 59/HMYNS

Ose ose rere
Iwo ojo simi
Oye kafi ojokan fun Olorun rere
B'ojomi ba mekun wa, iwo noju wa nu
Iwo ti sojo ayo, Emi fe dide re

Ose Ose rere
aki'yo sise loni
A o fise wa gbogbo fun aisimi ola
Didan loju re ma ndan, wo arewa ojo
B'ojo mi so ti laala, iwo nso ti isimi

Ose Ose rere
Ago tile nwipe,
feleda re lojokan, to fun o lojo mefa.
A o fise wa sile, lati losin nibe,
Awa ati ore wa, A o lo sile adua


Ose ose rere
Wakati re wumi,
Ojo orun niwo nse, wo apere orun
Oluwa he kin jogun simi leyin iku
Kinle ma sin o titi, pelu eniyen re....Amin

Комментарии

Информация по комментариям в разработке